Mo bẹru agba by King Sunny Ade (Lyrics & Translation)
Click here to watch Mo b'ẹru agba by King Sunny Ade (Lyrics & Translation)
Mo b’ẹru aagba (mo b’ẹru agba, mo b’ẹru agba o)
I’ve due respect for elders (I respect elder, I respect elder)
Ai b’ẹru agba ni o jaiye o gun
The world’s instability stems from lack of respect for elders
Ẹlẹgbẹ mo ni mo b’ẹru agba
Colleagues, I give due respect to elder
Agba n’bọ wa kan ẹ o ee
You’ll soon be an elder
Agba n’bọ wa kan ẹ o o laiye nbi
In this life, you’ll also be an elder
Agba n’bọ wa kan ẹ o e
You’ll soon be an elder
Aye o o o (Aye o, Aye o e)
Such is life (Such is life)
Aye o o o (Aye o, Aye o e)
Such is life (Such is life)
Oṣika, ranti ọjọ atisun rẹ o e
Evil doer, remember the day of your death
Iwọ ọdalẹ, ranti ọjọ atisun rẹ o e
You betrayer, remember the day of your death
Ẹni s’ebi (ibi lo mi a j’ere fun)
Evil doers (You shall reap evil)
Ẹni ba tun se ka nkọ o
What of evildoers ?
Ika lo mi a j’ere fun
Evil shall be their rewards
Bo ba wu ẹ ko s’ere
If you like, be kind
Rere lo mi a j’ere rẹ
Kindness shall be your reward
Bo wu ẹ ko se ka o
If you want, inflict evil on others
Ika lo mi a j’ere rẹ
Evil shall be your reward
Bofẹ bofẹ
Whether you want it or not
Ẹsan a ke lori ẹ
You’ll reap what you sow
Bofẹ bofẹ
Whether you want it or not
Ẹsan a ke lori ẹ
You’ll reap what you sow
Ọdalẹ se o ngbọ (ẹsan a ke lori rẹ)
Betrayer, can you hear ? (you’ll reap what you sow)
Njẹ mo ti sa keke mo mu re ‘gbo ifa
I ran quickly to ifa (priest) bush
Mo pa’ja mo mu re ‘di ọpẹ
I got set to my way to the palm tree
Mo sa keke mo mu re ‘gbo ifa
I ran quickly to ifa (priest) bush
Mo pa’ja mo mu re ‘di ọpẹ
I got set to my way to the palm tree
Ọpẹ mi titi mo se b’ojo lo rọ
The palm tree shook, I thought it was raining
Ojo pami lapa kan d’apa kan si
Rain, beat me at one part, leave the other part
Ojo pa mi o mase p’orẹ mi
Rain, beat me, not my friend
Ah agbo ‘ba mi digi ogi
…..
Tio loko tiolo
….
D’igi ogi e
…
Tio loko tiolo
…
D’igi ogi e
…
Tio loko tiolo
…
D’igi ogi
…
Tio loko tiolo
…
Agbo ‘ba mi digi ogi sẹ o o o o
…
Tio loko tiolo
…
Tio loko tiolo mukulumukẹ
…
Tio loko tiolo
…
Agbo ‘ba mi digi ogi ye
…
Tio loko tiolo
…
Tio loko tiolo ye
…
Tio loko tiolo
…
Rasaki ijo ti ya o
Rasaki, it’s time to dance
Tio loko tiolo
…
Agbo ‘ba mi digi ogi
…
Tio loko tiolo
…
D’igi ogi yẹn (Tio loko tiolo)
…
Agbo ‘ba mi digi ogi yẹn
…
Tio loko tiolo
…
Mukulumukẹ (ijo ti ya o)
… (It’s time to dance)
Tio loko tiolo
…
Mukulumukẹ (ijo ti ya o)
… (It’s time to dance)
Tio loko tiolo
…
Mukulumukẹ (ijo ti ya o)
… (It’s time to dance)
Tio loko tiolo
…
Ah…
https://youtu.be/0u1ijvl0Ups
Compiled by Ganiyu Ayanniyi M.
Comments
Post a Comment