YORUBA BY KING SUNNY ADE (LYRICS & TRANSLATION)


Ẹyin ọmọ Yoruba, mo kii yin mo ka go o

Yoruba indigenes, I greet you with utmost respect


Ẹyin ọmọ Yoruba, mo kii yin mo ka go o

Yoruba indigenes, I greet you with utmost respect


Onile, alejo, agba, at’ọmọde

Landlords, strangers, elders and children


Mo kii yin mo ka go o

I greet you with utmost respect


Ẹyin ọmọ Yoruba, mo kii yin mo ka go o

Yoruba indigenes, I greet you with utmost respect


Ẹyin ọmọ Yoruba, mo kii yin mo ka go o

Yoruba indigenes, I greet you with utmost respect


Onile, alejo, agba at’ọmọde

Landlords, strangers, elders and children


Mo kii yin mo ka go o

I greet you with utmost respect


O digba, a dupẹ lọwọ yin

Bye, thank you


Fun Ibanigbọrọ yi o

For listening to us


Ẹ ko’re kalẹ

Pay respect


O tun d’igba omiiran o

See you next time


Ipade wa, yoo ma dun yungba

Our reunion would be sweet


Yungba bi oyin

Sweet as honey


O d’igba o, o d’igba omiran o

Bye, see you next time


Ẹyin ọmọ ibilẹ, a kii yin o digba o

All Indigenous, we greet you, bye


O d’igba o, o d’igba miran o

Bye, see you next time


Ẹyin ọmọ ibilẹ, a kii yin o digba o

All Indigenous, we greet you, bye


O d’igba o, o d’igba omiran o

Bye, see you next time


Ẹyin ọmọ ibilẹ, a kii yin o digba o

All Indigenous, we greet you, bye


O d’igba o, o d’igba miran o

Bye, see you next time


Ẹyin ọmọ ibilẹ, a kii yin o digba o

All Indigenous, we greet you, bye


Compiled by Ganiyu Ayanniyi M.

Comments

Popular posts from this blog

HISTORY OF EJIGBO AND ITS KINGS

EJIGBO ANTHEM (Audio & Lyrics)

ELGASA WRITES TO CONCERNED AUTHORITIES ON PROPOSED FCE IN OSUN STATE