Posts

Showing posts from March, 2019

ITAN NIPA HUBERT OGUNDE (YORUBA)

Image
Ohun un to yẹ ko mọ nipa Hubert Ogunde: # Ọjọ Kẹwaa, osu Keje, ọdun 1916, eyiun ọdun mejilelọgọrun (102) sẹyin ni Hubert Ogunde fi ori sọlẹ si ilu Ọ̀sọsà, nipinlẹ Ogun Jeremiah Deinbọ ati Eunice Owotusan Ogunde lo se ọkọ rẹ wa sile aye, Olusọagutan si ni baba rẹ. # Ọdọ baba iya rẹ to jẹ onifa, ni Hubert gbe fun igba kan, eyi to mu ko mọ nipa Ifa, Ogun atawọn orisa abalaye miran Ogunde sisẹ lẹyin to pari iwe mẹfa rẹ tan bii olukọ ile ẹkọ alakọbẹrẹ, ọga akọrin ni sọọsi ati atẹduru # Ẹgbẹ Eegun Alarinjo lo fi bẹrẹ isẹ tiata, ko to dara pọ mọ isẹ ọlọpaa, o si de ipo Kọsitebu, ko to fẹyinti Oun lo kọkọ mu ere tiata wọ inu ẹgbẹ alarinjo, eyi to sọ di oludasilẹ ere tiata Lara awọn ere onise to se ni ‘Human Parasites’, eyi to fi n tako iwa sisare lati ra asọ ẹbi olowo iyebiye tii se ara ara Yoruba Ogunde jẹ ajijagbara fun iran Yoruba ati Naijiria, lati ipasẹ ọpọ ere to se fi tako awọn oyinbo amunisin. Lara ere naa ni ‘Bread and Bullet’ to se lọdun 1950. # Ogunde tun maa n lo e

WAPNIYI RECRUIT PAGE 2019

Do you really want to work with us ? Do you have passion in writing, journalism, online broadcasting ? If yes, fill the form below. You will be duly contacted for screening if selected. Loading...

All you need to know about 'TINTI'. It's real !!!

Image
Timigrace Institute For Teenagers Initiative (TINTI) TINTI is an institute created to make teenagers and youths come to the knowledge of the illness of premarital sex, teenage pregnancy and adolescent motherhood. TINTI is an institute with several visions but the motherly vision that births the other ones is; To reduce teenage pregnancy and adolescent motherhood in Nigeria, francophone and lusophone countries and if possible the world at large. For sometimes and now TINTI is known for; Sensitising teenagers on the effects of premarital sex, encouraging teenagers to focus on the pursuit of excellence rather than involving premarital sex and if at all we have any that have involved in this act and result to teenage pregnancy, TINTI also made provision for them by encouraging them to rise up and develop skills for immediate and future survival and how does this institute carry out these goals? TINTI visits four schools both primary and secondary schools in a year aside any